[Music + Lyrics] Gideon Adegboyega – Ileri Oluwa

 
Nigerian gospel music minister and saxophonist, Gideon Adegboyega releases new single “Ileri Oluwa“.

Are there promises GOD has made to you and at the moment it seems those promises will not be fulfilled?

Don’t give in to that trick, GOD’s promises will always come to fruition.

This song will help build your faith to stay until you access GOD’s promises for you.

Listen and download below;



LYRICS: Gideon Adegboyega – Ileri Oluwa

IleriOluwa
Odidandan IleriOluwa ni lati se
Odidandan IleriOluwa ni lati se
Boti wu kori, IleriOluwa ni lati se
Oti se leri, IleriOluwa ni lati se

Verse
Ileri ti baba se ko ni ye
Bekun pe da le kan ayo nbo lowuro odamiloju oo
Agan ma ronu mo o
Oluwa loun fun ni lomo
Beniyan ba fun ni, Afi shiregun
Bi esu ba fun ni, a odogun
Roju duro da siko Olorun
To le ro e lorun, o te ni lorun o
Toripe, oti se leri
Botiwukori
Mo Mo pe ko kin ja ni Kule rara o

Chorus
Odidandan IleriOluwa ni lati se
Odidandan IleriOluwa ni lati se
Boti wu kori, IleriOluwa ni lati se
Oti se leri, IleriOluwa ni lati se

Bridge
Baba boju ire wo mi
Jowo sekun mi derin
Lana nibi ti Ona osi
Fona Han mi Olohun Oba

- - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - -- - - - - - - - -
Promote your music /videos with us @kgospelmusic
 
OUR PROMO FEATURES INCLUDE:
🔸Your song gets featured on over 10 multiple music websites
🔸30-45sec Kgospelmusic Reels Video Lyrics Caption for (Instagram & TikTok)
🔸Repost on our social handles

We would love to work with you and to get started
Kindly send us a DM or call us at +2348068724282 for our promotion checklist
Previous Post Next Post